Document 316992

E ba wa dele
E mo nipa wa
ba wa sise Adiresi wa
E polowo oja yin
AKEDE Agbaye
Idanileko ALAROYE
Martins gba ami-eye meji laarin ose kan
Bi o ba fe
Awon Iroyin to se koko
Taofik Afolabi ati Soyemi Oluyinka
Wahala l’Ondo: Mimiko
A
pada si PDP, lawon
tamatase eôgbeô agbaboôoôlu Super Eagles teôleô, O·bafeômi Martins, tun ti gba awoôoôdu
meji laarin oôseô kan bayii lorileô-ede Ameôrika to ti n sôe beôbeô loôwoôloôwoô fun Kiloôoôbu
Seattle Sounders.
O·joôboô, Toôsde, ni ileesôeô oôkoô baalu Etihad Airways fun un lami-eôyeô agbaboôoôlu to dangajia
ju, beôeô lo gba awoôoôdu eôni ti goolu reô daa ju loôseô koôkandinloôgboôn saa igbaboôoôlu yii.
Martins lawoôn ololufeô boôoôlu l’Ameôrika dibo fun geôgeô bii eôni to gba boôoôlu to daa ju woôle
loôseô to koôja, eyi to gba iru reô loôseô keje, oôseô keôjoô, oôseô koôkanla ati oôseô keôrinlelogun.
O·dun to koôja ni Martins darapoô moô Seattle Sounders, nibi to ti gba boôoôlu meôtalelogun
woôle ninu ifeôseôwoônseô meôtadinlaaadoôta. O ti gba boôoôlu lorileô-ede Italy, Germany ati
England teôleô, gbogbo awoôn kiloôoôbu woônyi lo si ti sôe beôbeô manigbagbe
omo egbe ba gba kootu
lo
Ose to n bo ni won yoo
bura fun Fayose
Iku oga onimoto l’Ekiti:
Awon olopaa ti mu
eeyan mokandinlogun
Ajo CLP kilo fawon
oloselu lati faaye gba
awon obinrin
Pata okunrin ni mo
maa n ba lori beedi
temi atiyawo mi n
sun—Oke
Nitori wahala gbogbo
igba, igbeyawo odun
meeedogun tuka
n'Ileefe
E tun pade wa lori ero
E wa awon iroyin wa